Перейти к содержимому

Bisimanuel - Aanu Ni (Lyrics)

ColorFul Music

0:00 / 0:00

Bisimanuel - Aanu Ni (Lyrics)

68 443 просмотра · 2 месяца назад
ColorFul Music
2,22 тыс. подписчиков
68 443 просмотра · 2 месяца назад
Lyrics: Ohun t’awon kan gbawe fun Lo se were Omi ti won ni ko le san To wa di ibu Mo ni bo se n s'ola re o Oun loye Anu ni o A se iru emi le joba Owi ninu oro re, mo gba be A se ireti tun wa fun gi agelori O boro re mu, mo gba be Omi odo to kan d'ele pada dun Gege bi oro re, mo gba be Anu ni Anu ni Ohun t’awon kan gbawe fun Lo se were Omi ti won ni ko le san To wa di ibu Mo ni bo se n s'ola re o Oun loye Anu ni T’oba je ile mo ti wa Ko le kan mi Won ni no be hin turn Owo yen so wipe kan gbe fun mi Ere asapojude ti gbogbo won sa de fori mi Aidе mo wa wu mi o ku da ise olorun duro Ko da ise olorun duro o I was barely whispеring Your name Didn’t even know the words to say But somehow doors just opened up for me Like You were waiting where I’d be And I don’t understand it Thats the flavour of mercy Ohun t’awon kan gbawe fun Lo se were Omi ti won ni ko le san To wa di ibu Mo ni bo se n s'ola re o Oun loye Anu ni