SUNDAY IGBOHO WOJU SEYI MAKINDE LORI IWA EGAN TO WU SI AARE BOLA TINUBU
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
SUNDAY IGBOHO WOJU SEYI MAKINDE LORI IWA EGAN TO WU SI AARE BOLA TINUBU
1 020 просмотров · 3 ч назад
DriveTv Yoruba
16,3 тыс. подписчиков
1 020 просмотров · 3 ч назад
SUNDAY IGBOHO WOJU SEYI MAKINDE LORI IWA EGAN TO WU SI AARE BOLA TINUBU
Sunday Igboho korò ojú sí Gomina Seyi Makinde lórí ìwà ẹ̀gàn to wu sí Ààrẹ Tinubu
Àwọn janduku Fulani fọ̀rọ̀ wá Àwọn Ọmọ Ẹgbẹ́ Iru Ekun lenu wo Lẹ́yìn tí wọ́n dé wọn mọ́lẹ̀, Wọ́n ni àwọn tí ni kí wọ́n Jínà sí Bani, Ìpínlẹ̀ Kwara
Orisirisi Ọ̀rọ̀ lo tí ń wáyé lórí awọn Pásítọ̀ to sọpe àwọn lọ Sọ̀run, àwọn rí Jésù Kírísítì, àwọn kan ni ó ṣeé ṣe bẹ́ẹ̀, àwọn kan ni ona èké ni
Bí ìdílé olóògbé Toluwanisings ṣe ń gbìyànjú láti fara dà ìbànújẹ́ ńlá náà ní èdè aiyédè bá besile lórí ibi tí wọ́n o sì olóògbé náà si
Rolls-Royce ọkọ olowo iyebiye ti okunrin Ọlọ́rọ̀ Kan ra pe ki won o ba gbe ranṣẹ latoke okun dé losẹ̀ mẹ́ta lẹ́yìn ikú rẹ̀
Woli Agba àti Dele Omo Woli seleri láti gbé igbésẹ̀ òfin sí Àwọn tó n tan Ìròyìn èké kiri pé awọn lọwọ nínú Ikú Toluwanisings
Àwọn Ará ìlú Aramoko-Ekiti àti Ìgbìmọ̀ Alara rawọ ẹ̀bẹ̀ si Ooni ile Ifẹ̀ láti báwọn dá sí ọ̀rọ̀ yíyan Alara Tuntun tí kò lójú mọ
Ajọ NCDC tí buwọ́lu ọgọ́rùn egberun náírà ọ̀sẹ̀-ọ̀sẹ̀ fún àwọn tó ti lùgbàdì ààrun Ebola ní Nàìjíríà láti lè dènà itankale rẹ
Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kogi bẹ̀rẹ̀ iwadii lẹyin ti ọlọpaa kan yinbọn pa akegbe rẹ lobinrin kí o to pa ara rẹ naa
- OPC Mú Ọkùnrin afurasi Kan tí wọ́n fura sí pé ó jẹ́ janduku ọ̀daràn pẹ̀lú Ìbọn AK-49 ní agbègbè ijoba ibile oríre Ogbomoso
Ileeṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Delta tí mu Awakọ̀ Bọ́ọ̀sì Ilé-ẹ̀kọ́ kan pelu esùn Ìjínigbé àti ìfipá ba Ọmọbìnrin Ọmọ Ọdún mẹ́rìnlá kan ló pọ
drivetvnews
drivetv news
drivetv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog