GANI ADAMS FE PA MI! WON ATTACK MI PHYSICALLY ATI. SPIRITUALY.
NEWSCREST TV
0:00 / 0:00
GANI ADAMS FE PA MI! WON ATTACK MI PHYSICALLY ATI. SPIRITUALY.
1 804 просмотра · 1 день назад
NEWSCREST TV
12,9 тыс. подписчиков
1 804 просмотра · 1 день назад
Haaa! Gani Adams fe pa mi! Won kolu mi lara nipa emi! Kilo gan-an lo sele laarin Gani Adams ati awon to n fi esun kan an pe won kolu oun nipa emi? Se otito ni pe awon kan n gbogun ti oun ni ona emi, tabi asiri miran tun wa leyin oro yi?
Ninu fidio oni, a yoo jiroro lori oro to n fa ariyanjiyan yii, ohun ti won so nipa Gani Adams, ati awon ibeere to tun n duro de idahun. Tani o n so otito, ki ni gan-an si sele?
Wo fidio naa titi de opin, fi ero re sile ninu apoti asoye, ki o si ma gbagbe lati SUBSCRIBE, LIKE ati SHARE fun awon iroyin tuntun ati awon koko to n sele ni ile Yoruba.
*E JEKI A MO ERO RE NIPA ORO YI!*
#GaniAdams #GaniAdamsNews #GaniAdamsLatest #IroyinYoruba #IroyinLoni #YorubaNews #AareOnaKakanfo #IleYoruba #AsiriGaniAdams #IroyinNigeria #YorubaUpdates #LatestNews