Перейти к содержимому

LORI ISINKU TOLUWANISINGS IYAWO ATI EBI TI FENU KO NI WASIU AYINDE BA PARI IJA MC OLUOMO ATI SEGO

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

LORI ISINKU TOLUWANISINGS IYAWO ATI EBI TI FENU KO NI WASIU AYINDE BA PARI IJA MC OLUOMO ATI SEGO

3 776 просмотров · 1 дн. назад
DriveTv Yoruba
16,4 тыс. подписчиков
3 776 просмотров · 1 дн. назад
LORI ISINKU TOLUWANISINGS IYAWO ATI EBI TI FENU KO NI WASIU AYINDE BA PARI IJA MC OLUOMO ATI SEGO Leyin ọlọ́kàn òjò kan ariwo Ìyàwó àti ẹbí Toluwanisings ti fẹnu kò lórí ibi tí wọn yóò sin okú rẹ̀ sí Ayalegbeni ni àárẹ̀ Tinubu ni Aso rock, ogún ọmọ Naijiria ni, owo gbogbo wa si ni wọn fi kò, Sowore lo sọ̀rọ̀ síta bẹẹ Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ipinlẹ Oyo mú afurasí olè tó ń fọ́lé ní Ìbàdàn, wọ́n gba ẹrù toto ₦16.22 mílíọ̀nù padà lọwọ re Leyin ọlọ́kàn òjò kan ariwo Ìyàwó àti ẹbí Toluwanisings ti fẹnu kò lórí ibi tí wọn yóò sin okú rẹ̀ sí Gómìnà Seyi Makinde so ìdí to fi padá lẹ́yìn Ààrẹ Tinubu lẹ́yìn to ṣe atilẹ́yìn fun nínú ìdìbò ọdún 2023 Tinubu sọ pé Allah ni Olùfúnni ni ipo agbára to si le gbà agbára oṣèlú padà lọwọ ẹni to wa, leyin irinajo rẹ sì kaaba Àwọn dókítà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ dáwọ́ ìyanṣẹ́lódì dúró lẹ́yìn ọṣẹ kan, wọ́n padà senu ìṣẹ́ bí ìjíròrò ṣe ń tẹ̀síwájú pelu awon Aláṣẹ Ìjọba Àpapọ̀ ṣe ifilole ètò SPARK pelu koodi USSD láti jẹ́ kí àwọn ọmọ Nàìjíríà rí eyawo gbà nípasẹ̀ fóònù alágbèéká wọn KWAM 1 tún ṣe ipate àlàáfíà láàárín MC Oluomo àti Tafa Sego o kéde pé kò sogun mọ, bẹ́ẹ̀ ni kosija mọ Àwọn amokun seka ẹ̀dá gún àwọn ọmọdé márùn-ún lobe níbi ayẹyẹ Halloween, ileeṣẹ ọlọpaa bẹ̀rẹ̀ iwadii Lẹ́yìn wákàtì díẹ̀ tí wọ́n kéde ikú ọkọ nípìńlẹ̀ Ogun, ni ìyàwó rẹ̀ náà bá fò sanle toun naa si jáde láyé Kọmíṣọ́nà fún Ètò isuna àti Ìdàgbàsókè ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ayobami Ọjọ́, tí kọ̀wé fi ipò rẹ sílẹ̀ nínú ìjọba gómìnà makinde drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog