SEYI MAKINDE TI TU ASIRI AWON TO SEKOLU SI IYAWO SHARAFADEEN ALLI ATI AWON OLORI EGBE AWON
DriveTv Yoruba и DriveTV
0:00 / 0:00
SEYI MAKINDE TI TU ASIRI AWON TO SEKOLU SI IYAWO SHARAFADEEN ALLI ATI AWON OLORI EGBE AWON
1 641 просмотр · 5 ч назад
DriveTv Yoruba и DriveTV
1 641 просмотр · 5 ч назад
SEYI MAKINDE TI TU ASIRI AWON TO SEKOLU SI IYAWO SHARAFADEEN ALLI ATI AWON OLORI EGBE AWON
àwọn aṣiwèrè nìkan ló máa dìbò fún Tinubu ní ọdún 2027, Rotimi Amaechi lo foun lédè bee
Gómìnà Makinde tí ṣàlàyé pé àwọn ọmọ ẹgbẹ́ APC ló sekọlu si ìyàwó Sharafadeen Alli àti àwọn olórí ẹgbẹ́ náà
Primate Elijah Ayodele sọ pé ètò ìjọba Tinubu láti dín owó epo kù fún ọgbọ̀njọ́ fi hàn pé modaru wà nínú ìjọba.
Onanuga ṣàlàyé ìyàtọ̀ láàárín ẹ̀dinwó èrè lórí epo àti ìrànlọ́wọ́ owó epo láti ọ̀dọ̀ ìjọba
Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ipinlẹ Nasarawa rọ àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú láti dá ìpolongo ìbò wọn dúró fún ìgbà díẹ̀ nítorí ààbò aya Ààrẹ
Oshiomhole béèrè lọ́wọ́ Peter Obi nípa bí ó ṣe fi 150 mílíọ̀nù doola pamọ́ nígbà tó wà nípò gómìnà Anambra
Adewole Adebayo fi ẹ̀sùn kan ìjọba Tinubu pé ó dà bí ẹni pé ọ̀rọ̀ ó ye wọn mọ látàrí ọ̀rọ̀ ètò ẹ̀dinwó owó epo
Isaac Fayose rọ àwọn ọmọ Nàìjíríà láti fimo ṣọ̀kan, kí wọ́n sì dìbò yọ Tinubu kúrò nípò ní ọdún 2027
Ègbé òṣèlú ADC sọ pé ìjọba Tinubu ń dáhùn sí àwọn àbá wọn àti ti Atiku Abubakar lórí ọ̀rọ̀ epo rọ̀bì
Olárewaju fẹsun kan Aarẹ Tinubu pé o jí èrò Atiku lórí ìrànwọ́ owó epo rọ̀bì
drivetvnews
drivetv news
drivetv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog