Перейти к содержимому

OMASE O! IROYIN TO N TE WA LOWO NI PE AKORIN EMI OMO NAIJIRIA TOLUWANISINGS TI JADE LAYE

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

OMASE O! IROYIN TO N TE WA LOWO NI PE AKORIN EMI OMO NAIJIRIA TOLUWANISINGS TI JADE LAYE

892 просмотра · 7 ч назад
DriveTv Yoruba
16,2 тыс. подписчиков
892 просмотра · 7 ч назад
OMASE O! IROYIN TO N TE WA LOWO NI PE AKORIN EMI OMO NAIJIRIA TOLUWANISINGS TI JADE LAYE Ilé ẹjọ́ gíga apapọ gbọ́ ẹjọ́ Ẹgbẹ́ Ansaru to jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ní Ọ̀yọ́ láti fi fipá mú ìjọba láti tú àwọn olórí wọn sílẹ̀ Àwọn tórí kó yọ níbi ìjínigbe ìpínlẹ̀ Niger ṣàlàyé pé Ajínigbé yìnbọn pa awakọ̀, èèyàn mẹ́rin móríbọ́, méjìlá wà nìgbékùn Ileeṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ mú àwọn afurasí mẹ́fà tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ adigunjale nílu Ìbàdàn* Olupejo sọ nílé ẹjọ́ pé òun san ₦69.15 mílíọ̀nù fún Blessing CEO láti yà ilé fún ọdún márùn-ún Idí e ti Tinubu fi yan omo Yorùbá láti darí ẹ̀ka méjì gbóògì nínú àjọ elétò ìdìbò INEC gbodo di mimo fun gbogbo wa o - Atiku lo sọro soke bee. Oga agbà olopaa IGP Disu buwọlu Ìgbéga Ipò awọn ikọ Ọlọ́pàá tó n Ṣàkóso irinna lójú pópó. Adewale Adebayo ké sí ìjọba pé kí wọ́n tú àwọn olufẹ̀hónúhàn márùn-ún tó wo aso “Tinubu Must Go” sílẹ̀ ní Borno àwọn igi lẹ́yin ọgbà fún gómìnà Seyi Makinde méje tí padà kúrò lẹ́yìn rẹ̀ Ilé ẹjọ́ ti fagilé ẹ̀sùn mẹ́jọ tí ìjọba àpapọ̀ fi kan Adeniyi Adeyemi lórí ẹ̀sùn pé ó ṣe ìdásílẹ̀ àjọ èké Wike je ko di mímọ̀ pé inú gomina ipinle River, Sim Fubara dún sì ajọṣepọ àwọn ‎Ìròyìn to ń tẹ wá lọ́wọ́ ni pé akọrin emi ọmọ Nàìjíríà, Toluwanisings, ti jáde laye drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog