Перейти к содержимому

AWON JANDUKU SE IKOLU SI OKO GOMINA ADEMOLA ADELEKE NI OSOGBO NI ORO BA DI GBASGBOS

DriveTv Yoruba

AWON JANDUKU SE IKOLU SI OKO GOMINA ADEMOLA ADELEKE NI OSOGBO NI ORO BA DI GBASGBOS

5 933 просмотра · 2 дня назад
DriveTv Yoruba
14,8 тыс. подписчиков
5 933 просмотра · 2 дня назад
AWON JANDUKU SE IKOLU SI OKO GOMINA ADEMOLA ADELEKE NI OSOGBO NI ORO BA DI GBASGBOS Eberu Ọlọ́run óò, Baba wa ó kú ó, àwọn ọmọ Ogogo ló jáde sọ̀rọ̀ leyin ìròyìn kan tó ń lọ pé àgbà ọṣèré náà tí jáde laye Ijawe olubori Adeleke kò rọrùn rárá nitori pe Ógùn ni eto idibo naa pelu kikoju, gomina mẹ́tàdínlógún àti senito àádọ́ta, Davido lo sọ̀rọ̀ síta bẹẹ Sanwo-Olu Sanwo ẹko o, fún bi o se fun àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ LASU tí wọ́n jáde ní ipele àkọ́kọ́ first class ní Ogun Millionu N20m fún ẹnì kọ̀ọ̀kan Lakọkọ ni iro Ìbọn ndun o lasiko tàwọn afurasí janduku oloselu kan ṣe kọlu si ọ̀kọ̀ Gómìnà Adeleke lOsogbo Ohun to ba gbà lama fun pẹ̀lú Tani Olorun o, nínú kó lọ sẹ́wọ̀n tí ọwọ́ òfin bá tẹ̀ ẹ́, tàbí ká fìdí rẹ̀mi nínú igbẹjọ re - Agbejọ́rò O.S Imam Eberu Ọlọ́run óò, Baba wa ó kú ó, àwọn ọmọ Ogogo ló jáde sọ̀rọ̀ leyin ìròyìn kan tó ń lọ pé àgbà ọṣèré náà tí jáde laye Dangote àti Ọ̀pọ̀ àwọn looko looki lope mi lakoko ìdìbò gómìnà Ìpínlẹ̀ Osun to kọjá láti pa àwọn ohun tí mo kò soju òpó ayélujára mi rẹ, Davido ló ṣàlàyé síta bẹẹ Owo Igbo wogbo o, fun bi àjọ NDLEA se dana sun egbogi oloro, gbẹ́sẹ̀ lé cocaine ti iye re to $28m ti won gbé lọ sí ilẹ Ọba UK. Tinubu tí darapo mọ ẹka ìdájọ́ orile-ede Amerika láti bèrè àfikún òjò mewa láti pèsè àwọn akọsílẹ̀ nípa esun tí wọ́n fi kan pé òní ibaṣepọ pelu gbígbé ògùn oloro* Senator Fadahunsi tọrọ àforíjì o, fún àwọn ọ̀rọ̀ abuku tó so láàfin Owa ilẹ Ijesa pe omo egbẹ Acourd tawon bari pipa ni, o ni aigbora ẹni ye lo fa Haaa o ma se o, Ojajuni Justice oludije dupò aṣojú nIle igbimọ asofin Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo lẹgbẹ oselu AAC jade laye. drivetv drive tv drivetvnews drive tv news drivetv news drivetv yoruba drive tv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog