Перейти к содержимому

🚨 IMAM ILORIN JÁDE TAN!“KÍ NI Ẹ̀ṢẸ̀ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ?

MIGHTY CHANNEL VISUALS

0:00 / 0:00

🚨 IMAM ILORIN JÁDE TAN!“KÍ NI Ẹ̀ṢẸ̀ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ?

328 просмотров · 7 часов назад
MIGHTY CHANNEL VISUALS
8,36 тыс. подписчиков
328 просмотров · 7 часов назад
🚨 IMAM ILORIN JÁDE TAN! “KÍ NI Ẹ̀ṢẸ̀ ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ?” Nínú Khutbah Jumu’ah tó lágbára, Imam Ilorin ń ṣàlàyé àwọn ojúṣe ìjọba sí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè, àti bí ìjọba ṣe yẹ kí ó ṣiṣẹ́ fún ààbò, ìdàgbàsókè, ìdájọ́ òdodo àti àlàáfíà àwọn aráàlú. 🇳🇬 Ọ̀rọ̀ tó yẹ kí gbogbo ọmọ Nàìjíríà gbọ́. 🎥 WO TÍTÍ DÉ ÒPIN, KÓ SÍ PINPỌ̀ PẸ̀LU ÀWỌN ẸLẸ́NI TÍ Ọ̀RỌ̀ YÌÍ LE RÁNTÍ. #ImamIlorin #Ilorin #Nigeria #KwaraState #Jummah #Khutbah #Government #Leadership #NigeriaToday