Перейти к содержимому

Brymo - Adèdótun (Lyrics)

Lyrica Sound

0:00 / 0:00

Brymo - Adèdótun (Lyrics)

27 334 просмотра · 4 г. назад
Lyrica Sound
636 подписчиков
27 334 просмотра · 4 г. назад
#Adèdótun #Yellow by Brymo #Yellow #Lyrics Spotify: https://open.spotify.com/track/1gOpMJ... Adèdótun Lyrics: Awon adan n fo loke Won fonka soju orun Un o maa mo ibi won nlo Eledua lo n seke won Ko keyin si e Ore ooo Ohun o n wa O wa niwaju re ooo Adédòtun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Awon adan n fo loke Nigba igba won kun oju orun Un o maa mo ohun wo n je Eledua lo n so won lo n bo won Ko pamo si e Ore ooo O wa lo Sokoto O waa lapo sokoto Adédòtun Oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Adédòtun O ooo oyindamola mi Ero gbogbo e ba n gberin Adédòtun ooo Ko pa mo si e Ore ooo Ohun o n wa Owa niwaju re ooo ooo