Перейти к содержимому

OWO ONIRU OWO ONIYO NI MO FI TO OMO MI TI WON JI GBE - IJOBA TINUBU E GBA WA O

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

OWO ONIRU OWO ONIYO NI MO FI TO OMO MI TI WON JI GBE - IJOBA TINUBU E GBA WA O

1 461 просмотр · 19 часов назад
DriveTv Yoruba
16,2 тыс. подписчиков
1 461 просмотр · 19 часов назад
OWO ONIRU OWO ONIYO NI MO FI TO OMO MI TI WON JI GBE - IJOBA TINUBU E GBA WA O Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun tí ṣèlérí pé àwọn ò fi ojú afurasi mẹta bá ilé ẹjọ́ fún esun sise ikọlu sì àwọn ọlọ́pàá ati dídá wọn dúró lenu ise wọn Tinubu rọ́ Àwọn Ọ̀dọ́ ọmọ Nàìjíríà Láti maa Sọ Èrò Wọn Nípa Ọ̀rọ̀ Orílẹ̀-Èdè lakoko to ń ṣe a sisile ìpàdé national youth confab todun 2026 Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ipinle Ogun tí Mú Ọkùnrin ẹni ọdún marundinlaadota Kan Nítorí Ẹ̀sùn Jìbìtì orí Ayelujara Miliọnu méjì abo naira Owo te Ọmọ Nàìjíríà kan tó pe nomba pajawiri 911 láti yàgò fún sísan owó oúnjẹ ni America Owó onírú owó oníyọ̀ ni mo fi tọ́ ọmọ mi tí wọ́n jí gbé Ìjọba e gbà wa o AMÒFIN AMẸRIKA KAN BA ORILE EDE NIGERIA YO LEYIN TI OWO TE OLORI ODARAN FULANI KAN Oluko kan ni ipinle eko ri ewon gbere he, leyin ti o ni ibalopo peju omo odun meji to je akeko re Báwo ni mo ṣe sá lọ lẹ́yìn tí àwọn ọkùnrin ológìbò kan jí àwọn ènìyàn mẹ́rìndínlógún gbé – Oníṣọ̀ọ̀ṣọ́ lo so bee. drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog