Перейти к содержимому

ITAN ILU INISA NI IPINLE OSUN (HISTORY OF INISA IN OSUN STATE)

Isedale Abinibi Wa

0:00 / 0:00

ITAN ILU INISA NI IPINLE OSUN (HISTORY OF INISA IN OSUN STATE)

2 390 просмотров · 4 года назад
Isedale Abinibi Wa
2,68 тыс. подписчиков
2 390 просмотров · 4 года назад
Èyí jẹ́ ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò tí Adéọlámi aya Ọlátúnjí ṣe pẹ̀lú Kábíyèsí Ọba Joseph Ọládùnjoyè Oyèdélé Fasikun II tí wọ́n jẹ́ Olúníṣà ti ìlú Ìníṣà ní ìjọba ìbílẹ̀ Odò Ọ̀tìn ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun lórí ohun tí ó bí orúkọ Ìníṣà, ìtàn ìlú náà, àwọn àwòmọ́ni ìlú náà àti àwọn ohun pàtàkì tó yẹ kí ẹ mọ̀ nípa ìlú Ìníṣà. Ẹ má gbàgbé láti darapọ̀ mọ́ wa (subscribe) lójú òpó YouTube yìí láti máa gbádùn àwọn ohun Ìṣẹ̀dálẹ̀ wa gẹ́gẹ́ bí ọmọ Yorùbá àtàtà. Ẹ ṣeun púpọ̀