Перейти к содержимому

HA! O MASE O, BUS OKO TO N GBE EGBE AGBABOOLU CROWN FC LO FUN IFESEWONSE NI IJAMBA, EEYAN KU

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

HA! O MASE O, BUS OKO TO N GBE EGBE AGBABOOLU CROWN FC LO FUN IFESEWONSE NI IJAMBA, EEYAN KU

729 просмотров · 4 ч назад
DriveTv Yoruba
16,3 тыс. подписчиков
729 просмотров · 4 ч назад
HA! O MASE O, BUS OKO TO N GBE EGBE AGBABOOLU CROWN FC LO FUN IFESEWONSE NI IJAMBA, EEYAN KU Haa o mase o, bọọsi, ọkọ to n gbé egbẹ agbabọọlu Crown FC lo fun ifesewonse ni ijamba ni Isagamu, èèyàn kan ku awọn mii si farapa APC kéde ètò ìpolongo rẹ̀ fún ìdìbò gbogbogbòò ọdún 2027, Tinubu yóò bẹ̀rẹ̀ ní Kaduna, yóò parí ní Èkó Obafemi George ṣàlàyé pé Tinubu ti bẹ̀rẹ̀ ìpolongo rẹ̀ láti ọdún mẹ́ta sẹ́yìn, kò nílò láti lọ sí gbogbo Ìpínlẹ̀ fún ìpolongo Kwankwaso sọ pé Peter Obi kò jẹ́ kí Tinubu lè sùn asun forí losuka mo nítorí ìdìbò ọdún 2027 tó ń bọ̀ Primate Ayodele kìlọ̀ fún Tinubu pé kò sora nitori àwọn kan lára àwọn tó yí ká lè jà á sílẹ̀ kí ìdìbò tó dé Ọ̀pọ̀ èèyàn farapa, ilé dàwó, látàrí ìbúgbàmù méjì tó wáyé ní Rivers àti Edo Atiku ṣe ìfilọ́lẹ̀ ètò kan tó máa jẹ́ kí àwọn ọmọ Nàìjíríà bi ní ìbéèrè nípa ìjọba àti ìlànà ètò rẹ̀ Rufai Oseni sọ pé Tinubu kò ní agbára tóto láti ṣe ìpolongo káàkiri Nàìjíríà ṣáájú ìdìbò 2027 ni, kii se ọgbọ̀n òṣèlú Onanuga satileyin fún àwọn ìlànà ọrọ̀ ajé ijoba Tinubu, o sọ pé owó àpò ìrẹsì ti sọ̀kalẹ̀ láti aadofa egberun sí aadota egberun Wike kesi àwọn ọmọ Nàìjíríà láti ṣe suuru, ó ní yíyanjú ìṣòro ọrọ̀ ajé Nàìjíríà kò dà bí ìtọ́jú aláìsàn Gomina Aiyedatiwa pasẹ ki wọn fi oogun apakororo sinu odo igbokoda fun ààbò awọn ara agbegbe naa Ọkùnrin ẹni ọgbọ̀n ọdún kan kú lẹ́yìn tí ìyàwó rẹ̀ gé nkan ọmọkùnrin rẹ̀ nítorí pé ò ń fi kinni rẹ jẹ dodo àwọn ọmọbìnrin kẹ̀kẹ́ miran ni Taraba drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog