SUNDAY IGBOHO GBA TANI OLOHUN LOWO AWON TO FE GBE LORO BAA DI GBASGBOS
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
SUNDAY IGBOHO GBA TANI OLOHUN LOWO AWON TO FE GBE LORO BAA DI GBASGBOS
3 583 просмотра · 2 дня назад
DriveTv Yoruba
15 тыс. подписчиков
3 583 просмотра · 2 дня назад
SUNDAY IGBOHO GBA TANI OLOHUN LOWO AWON TO FE GBE LORO BAA DI GBASGBOS
Wọn i ba gbe Tani Olohun de Kwara o Sunday Igboho lo kọ ki awọn Ọlọ́pàá o gbé lọ tori ki rogbodiyan o ma ba sẹlẹ n'Ibadan.
Ẹ o le gbe lọ o, ẹ o le gbe Tani Olohun lọ lariwo tawon èèyàn nilegbe Tani Olohun nílu Ibadan npa lasiko tawọn olopaa ti o wọsọ yabo ilegbé rẹ lati gbé janto lọ re kwara.
Àjọ JAMB kéde igbésẹ̀ tuntun pelu bí wọn ṣe ni awọn olukopa nínú idanwo UTME Le maa fi esi idanwo gírámà wọn ranṣẹ lórí ayélujára láti ilé wọn
Èso alaabo amotekun ipinlẹ Ondo dá ìṣe ijinigbé kan dúró, wọn si doola obìnrin kan àti àwọn ọmọ rẹ méjì ni ipinlẹ naa
Ẹgbẹ́ òṣèlú Accord Party ni ipinlẹ Osun tí kesi ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá Nàìjíríà láti mú DPO ikire pelu bí wọn ṣe ló lọ́wọ́ nínú rògbòdìyàn ìjà garaji to yọrí siku èèyàn méjì
Gbajugbaja Akéwì àti asun Ìjálá Olókìkí Loke-Ogun, Oloye Alabi Ogundepo, rẹ wálẹ̀ asa leni Ọmọ Ọdún merindinlaadorun
Àwọn ènìyàn tí bù ẹnu àtẹ lu Funke Akindele lórí ayẹyẹ ọjọ́ ìbí rẹ̀ tó ṣe lẹ́yìn ikú Ogogo àti bose pin àwọn àwòrán rẹ soju òpó ayélujára
Ajo UAG tí kesi kọmisọna ọlọpaa ipinlẹ Eko láti sá yí pada igbimo tuntun to ń ṣe wádìí ikú mohbad láti lè rídìí okodoro lórí ohun tó yí ikú rẹ ka
Ìjọba Àpapọ̀ orile-ede Naijiria ti kede láti ṣe àtúnṣe afárá carter bridge láàárín oṣu mẹ́rìnlélógún nítorí ipa tí ọ́nà náà ni ni ilu Eko
Wahala ti o sẹlẹ nikire to mu ki DPO ẹka agọ ọlọpaa to wa nikire o yinbọn sekupa èèyàn o mu agbaja lọwọ o, nse lo da bi pe DPO náà kan mọmọ fẹ feje èèyàn sofo ni.
drivetv
drive tv
drivetvnews
drive tv news
drivetv news
drivetv yoruba
drive tv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog