NO GOING BACK! AWON IGBIMO AFOBAJE ILU IWO ATI GOVERNOR ADELEKE TI YI OBA RASHIDI OLUWO NI IPO.
NEWSCREST TV
0:00 / 0:00
NO GOING BACK! AWON IGBIMO AFOBAJE ILU IWO ATI GOVERNOR ADELEKE TI YI OBA RASHIDI OLUWO NI IPO.
2 838 просмотров · 8 ч назад
NEWSCREST TV
14,1 тыс. подписчиков
2 838 просмотров · 8 ч назад
NO GOING BACK! Awon Igbimo Afobaje Ilu Iwo ati Governor Ademola Adeleke ti yi Oba Rashidi Oluwo ni ipo. Isele tuntun yii ti fa ifokanbale ati ifesi nla laarin awon eniyan Ilu Iwo ati gbogbo awon to n tele oro ijoba ibile ati awon oba ile Yoruba.
Kini gan-an lo fa ipinnu yii? Kini ipa ti awon Igbimo Afobaje Ilu Iwo ati Governor Adeleke ko ninu oro naa? Ati kini yoo sele si ipo Oba Rashidi Oluwo leyin gbogbo awon idagbasoke yii?
Wo fidio yii titi de opin fun alaye kikun lori oro naa, ki o si fi ero re sile ninu comment section.
#Iwo #ObaRashidiOluwo #GovernorAdeleke #OsunState #IwoNews #YorubaNews #OsunNews #YorubaKingdom #ObaYoruba #NigeriaNews #LatestNews #CurrentAffairs