Перейти к содержимому

HYMN 621

CCC Akoka Parish

0:00 / 0:00

HYMN 621

10 382 просмотра · 9 л. назад
CCC Akoka Parish
8,36 тыс. подписчиков
10 382 просмотра · 9 л. назад
HYMN 621 Maleka Mimo t'orun Nwon ti t'orun sokale Lati wa sure fun wa Ninu Ijo Mimo Enyin Omo Ijo Mimo Mura Lati se ife re Nitori O mbo Kankan Lati be wa wo Gbogbo 'enyin Oluponju E korin ke ho f'ayo Nitori Oluwa mbo Yio da yin nide Ayo wa yio ti po to Nikehin ni ijoba orun Bi awa ba le mura S'ise Oluwa Enyin Osise Oluwa Mura lati sise na Nitori ere nyin po Li oke orun (Amin)