Перейти к содержимому

A MAA HU OKU TOLUWANISINGS TI WON BA SIN SI OGBA ISINKU DIPO EGBE IYA RE - EBI FOHUN SILE

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

A MAA HU OKU TOLUWANISINGS TI WON BA SIN SI OGBA ISINKU DIPO EGBE IYA RE - EBI FOHUN SILE

1 012 просмотров · 6 ч назад
DriveTv Yoruba
16,4 тыс. подписчиков
1 012 просмотров · 6 ч назад
A MAA HU OKU TOLUWANISINGS TI WON BA SIN SI OGBA ISINKU DIPO EGBE IYA RE - EBI FOHUN SILE Atiku ni ona láti fà ojú àwọn ènìyàn mọ́ra ni aadorin egberun tí ìjọba fowo sì fún awọn Òṣìṣẹ́ Ìjọba gẹ́gẹ́ bí owó ọkọ̀ Ẹgbẹ́ oselu APC ni asigbo ọ̀rọ̀ ni Ọ̀rọ̀ Alwan Hassan tó n sopé àwọn Minisita máa ń san Bílíọ̀nù Naira láti dé ipò, wọn mi kise lábé ijoba Tinubu Ẹgbẹ́ YSDM tún pe fún ìdásílẹ̀ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Oduduwa, won dábàá aàlà fún awọn ti kii se mọ bibi ilẹ̀ Yorùbá Akpabio ṣalaye pé wọ́n ń sanwó fún awọn to ń bù ẹnu atẹ lu Tinubu lórí ẹ̀rọ Ayélujára ni, Ó Rọ awọn Ọ̀dọ́ Àríwá láti se Ìpolongo fún ṣáá kejì rẹ Kenneth Okonkwo tí ké gbàjarè sita pé Ìyàwó Segun Showunmi koye kò jẹ oludarí Ẹ̀ka Ìṣiṣẹ́ Ìdìbò INEC Ṣáájú Ìdìbò 2027 Ààrẹ Bola Tinubu tí kò lẹ́tà ibéèrè fún ẹ̀yáwó lágbàáyé, ó ń bereki ile ìgbìmọ̀ aṣòfin buwọ́lu lẹ́tà náà fun Itesiwaju Ààrẹ Tinubu dágbére Makkah fọ́mọ Nàíjíríà, láti lọ wà ojú Ọlọ́run fún Naijiria ati awọn eeyan rẹ Ẹbí Toluwanisings ṣalaye Pé awọn máa hu òkú rẹ tí wọ́n bá sin sílẹ̀ ìsìnkú dípò ẹgbẹ́ Ìyá rẹ̀ Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ TUC faake kọri, wọn tako àdéhùn N70,000 náírà tí ìjọba àpapọ̀ ṣèlérí, wọ́n bèèrè fún àfikún owó oṣù tuntun Ẹgbẹ́ oselu Action Alliance tí kesi INEC Láti Ṣèwádìí, kí o sì dá awọn Òṣìṣẹ́ to bá Kópa Nínú síṣe Àdàkọ NIN Àwọn Olùdìbò Pẹ̀lú AI Won Bumi, won fimi we igi Oko koda wo pemi lobo langido, ló jẹ́ kí n lọ bóra'..... Habibat Jinadu lo soro be. drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog