Перейти к содержимому

AWON OMO ISOTA PA ALATILEYIN ORIYOMI HAMZAT KAN - DELE OMO WOLI AGBA BA FARAYA LORI IKU TOLUWANISING

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

AWON OMO ISOTA PA ALATILEYIN ORIYOMI HAMZAT KAN - DELE OMO WOLI AGBA BA FARAYA LORI IKU TOLUWANISING

5 787 просмотров · 1 дн. назад
DriveTv Yoruba
16,3 тыс. подписчиков
5 787 просмотров · 1 дн. назад
AWON OMO ISOTA PA ALATILEYIN ORIYOMI HAMZAT KAN - DELE OMO WOLI AGBA BA FARAYA LORI IKU TOLUWANISING B'awo ba ku awo ni sedaro awo, awọn aworo sasa, ẹlẹsin ibilẹ, awọn ẹgbẹ oṣèré Tampan darapọ mọ ẹbí ologbe Ayanwọye Jẹkayinfa seto isinku ẹni wọ́n ti o rèwàlẹ̀ àsà. Ilé Ẹ̀jọ́ gíga ipinlẹ Bọ̀rno ti fi obìnrin kan sì ẹ̀wọ̀n ọdún méjì fún esun fífi ọmọbìnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínlógún sílẹ̀ fún ibalòpọ̀. ‎- Pasito ọmọlẹ́yìn figbeta, ó ní Ìta ti sú oun, oun fẹ́ẹ́ padà sílé òun tawọn tí kúrò láti oṣù karùn-ún nítorí ìbẹ̀rù bandiiti ‎- Ileeṣẹ Ọlọ́pàá Osun mú àwọn afurasí mẹ́fà míì tí wọ́n fura sí pé wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ ẹgbẹ́ òkùnkùn ‎- Ọlọ́pàá fìdí ikú èèyàn kan múlẹ̀ lẹ́yìn tí àwọn ọmọ isota kọlu àwọn alatìlẹ́yìn Oriyomi Hamzat ní Ibadan ‎- Sam Amadi fẹ̀sùn kan Tinubu pé ó ń yẹra fún ìnira ìpolongo ìdìbò ọdún 2027, lose felo àwọn gomina ‎- Molebi toluwanisings tí kéde ipapoda re ‎- Tinubu tún da ìjíròrò sílẹ̀ lẹ́yìn tó pe ara rẹ̀ ní gómìnà níbi ìdásílẹ̀ ìgbìmọ̀ ìpolongo ààrẹ APC ‎- Ileeṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ gba àwọn ọmọ orile-ede Congo márùn-ún tí wọ́n fura sí pé wọn lugbadi òwò eru ‎- Àwọn alátìlẹ́yìn Atiku Abubakar fi Ààrẹ Tinubu ṣe ẹlẹ́yà lẹ́yìn tó pe ara rẹ̀ ní “Gómìnà” ‎- Dele Momodu fi Ààrẹ Tinubu wé olóògbé Sani Abacha, ó ní Tinubu ti ṣe ohun tó burú ju ti Abacha lọ ‎- Àwọn agbebọn pa òṣìṣẹ́ immigration kan ní Ìpínlẹ̀ Niger, wọ́n sì ṣe ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ léṣe ‎- Dele Omo Woli fara yà lori ikú gbajugbaja akọrin ẹmi Toluwanisings drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog