Перейти к содержимому

IJOBA IPINLE OSUN KILO FUN OLUWO TILU IWO LORI ORO ASOTAN RE TO LE DA WAHALA SILE NI GBORO

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

IJOBA IPINLE OSUN KILO FUN OLUWO TILU IWO LORI ORO ASOTAN RE TO LE DA WAHALA SILE NI GBORO

2 207 просмотров · 20 ч назад
DriveTv Yoruba
16,4 тыс. подписчиков
2 207 просмотров · 20 ч назад
IJOBA IPINLE OSUN KILO FUN OLUWO TILU IWO LORI ORO ASOTAN RE TO LE DA WAHALA SILE NI GBORO Seyi Makinde bù ẹnu atẹ lu awọn Olórí Nàìjíríà to Kọjá àti Àwọn towa lórí ipò, Ó ní won ó ní arojinle lórí ohun amusoro Orílẹ̀-èdè ‎‎- Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Kìlọ̀ Fún Oluwo láti dekun lórí àwọn Ọ̀rọ̀ tó lè dá Ìjà Ẹ̀sìn àti Ìforígbárí Láàárín Àwọn aráàlú Sílẹ̀ ‎- Ilé-ẹjọ́ wọ́gilé igun David Mark tó ń ṣàkóso ẹgbẹ́ òṣèlú ADC, wọn yọ Atiku gẹ́gẹ́ bí olùdíje sípò Ààrẹ Leyin esi latodo àwọn ìpínlẹ̀, Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà fẹ́ fi àbá ìdásílẹ̀ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ ránṣẹ́ sí Tinubu ‎- Ileeṣẹ Ọlọ́pàá Nàìjíríà tí Ṣèlérí Ààbò Fún Àwọn agunbaniro NYSC àti Àwọn Òṣìṣẹ́ ajọ eleto ìdìbò lakoko Ìdìbò Ọdún 2027 Ìjọba Ọ̀yọ́ tako ẹsùn pé Makinde Kórìíra esìn Islam, Ó ní Ìṣe Ènìyàn ló máa ń fi Òtítọ́ hàn ju ariwo lásán lọ Rufai Oseni Béèrè lórí Ìtàn Ìgbésí Ayé Tinubu tí kó jọ ra won, pelu bose ni òun wako ni Amerika àti Bose tí sọ tẹ́lẹ̀ pé òun jogún ọ̀rọ̀ lowo àwọn òbí oun Atiku Ṣèlérí Pé oun dá Ààbò to péye padà wá sí Nàìjíríà tí àwọn èèyàn bá dibo yàn òun nínú ìdìbò Ààrẹ Ọdún 2027 ‎‎‎- Oyinlola ni Tinubu àti Atiku dagba jù láti díje fún Ipò Ààrẹ, Ó ní kí wọ́n fi ayè Sílẹ̀ fún awọn Ọ̀dọ́