ORIYOMI HAMZAT FARAYA LORI BI WON SE PAA OMO EYIN RE KAN TORI ORO OSELU - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
ORIYOMI HAMZAT FARAYA LORI BI WON SE PAA OMO EYIN RE KAN TORI ORO OSELU - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY
2 881 просмотр · 10 часов назад
DriveTv Yoruba
16,3 тыс. подписчиков
2 881 просмотр · 10 часов назад
ORIYOMI HAMZAT FARAYA LORI BI WON SE PAA OMO EYIN RE KAN TORI ORO OSELU - DRIVETV YORUBA NEWS TODAY
Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ipinlẹ Ọ̀yọ́ Gba Ọmọ Ọ̀sẹ̀ Mẹ́rin kan sílẹ̀, Wọ́n mú afurasi méjì to lọ́wọ́ nínú títa Ọmọ Náà ni Mílíọ̀nù meji
Ẹgbẹ́ PBAT Door-to-Door Movement ni ipinlẹ Ọ̀yọ́ Gba ebun Ọkọ̀ Ìpolongo méjìlélọ́gbọ̀n, fún imura sílẹ̀ Ìdìbò 2027
Ìgbéraga Wà Nínú Ẹ̀jẹ̀ Rẹ̀ ni, kí wọ́n tó bí ní wón ti ń sere ìtàgé ni Naijiria” Kola Olaiya bu ẹnu atẹ lu Pete Edochie leyin ọ̀rọ̀ aṣáájú nínú ìṣe ere
- Oriyomi Hamzat fi ẹ̀dùn ọkàn rẹ hàn, ó ní Èróngbà oun láti tukọ̀ ìpínlẹ̀ Oyo kò tó nǹkan tí wọ́n ń gbẹ̀mí èèyàn si
Ehiozuwa Johnson Agbonayinma kò ìwé ìránnilétí sì àjò EFCC lati satunyewo ìwé ẹjọ́ ajebanu atiku
Àwọn Ẹlẹ́sìn Ìṣẹ̀ṣe nílu Ọ̀yọ́ rọ Àwọn Aráàlú Láti máa Bọ̀wọ̀ Fún Àwọn Ọba, Kí Wọ́n Sì máa dáàbò bo Àṣà Yorùbá
- “Òṣì ni Ìṣòro Pàtàkì ni Nàìjíríà, Kì Ṣe ọ̀rọ̀ Ẹ̀sìn” Makinde rọ Àwọn Kristẹni láti Kópa Nínú Òṣèlú
Makinde fẹsun kan ijoba Tinubu, ó ní o na owo NLNG to yẹ kí wọ́n pin fún àwọn ìpínlẹ̀
Àjọ EFCC ni owó tí tẹ Faisal Maina àwọn sí ń retí àṣẹ ilé ẹjọ́ lati gbe lọ sí ọgbà ẹ̀wọ̀n leyin towo tẹ nígbà to salo
Yoruba trending latest news today Monday 19th October 2026
drivetvnews
drivetv news
drivetv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog