Перейти к содержимому

ALHAJA KAOLA KAFILAT TI TU ASIRI TO ROMO VIDEO IBALOPO TI OKO RE GBE SITA

DriveTv Yoruba

0:00 / 0:00

ALHAJA KAOLA KAFILAT TI TU ASIRI TO ROMO VIDEO IBALOPO TI OKO RE GBE SITA

1 361 просмотр · 6 ч назад
DriveTv Yoruba
16,4 тыс. подписчиков
1 361 просмотр · 6 ч назад
ALHAJA KAOLA KAFILAT TI TU ASIRI TO ROMO VIDEO IBALOPO TI OKO RE GBE SITA Ààrẹ Tinubu balẹ ni Saudi Arabia Láti Ṣe Umrah, gẹgẹ ọ́nà láti gbàdúrà fún àláfíà orile-ede Naijiria Seyi Makinde bù ẹnu atẹ lu àárẹ̀ Tinubu lórí ìrìnàjò rẹ lọ Sí Saudi Arabia láti Gbàdúrà Fún Nàìjíríà ‎- Ẹgbẹ́ Àwọn òṣìṣẹ́ feyinti tí béèrè pé kí Tinubu fi awọn náà sínú eto Ìrànlọ́wọ́ owo Ọkọ̀ Oṣooṣù N70,000 tí ìjọba se ‎- Primate Ayodele Kìlọ̀ fún ẹgbẹ́ òṣèlú ADC àti Atiku Abubakar láti sún Ọjọ́ Ìbẹ̀rẹ̀ Ìpolongo Ìdìbò Wọn sì waju láti yẹra fún ewu àti idena ‎- Ọkọ̀ tí mo fe tẹ́lẹ̀ máa ń gba owó lọwọ mi koto bá ní ń kan pọ, kòda ó ṣe débi pé ofi fídíò ibalopo àwa méjèèjì sita, Alhaja Kaola lo sọ̀rọ̀ síta bee ‎- Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ ASUU, ẹ̀ka ti Lautech l'Ogbomoso bẹ̀rẹ̀ ìyanṣẹ́lódì aláìní gbedeke, wọn ni bìjọba o dàwọn lohun ise o se ‎- Idile Michael Oyedekun, olùkọ́ tí àwọn ajínigbé gé lórí l'Oyo kéde eto ìsìnkú olóògbé naa ‎- Lóòótọ́ lowo jáde lẹ́yìn tí mo gbìyànjú láti ṣoògùn owó àmọ́ wọ́n ní mi ò gbọdọ̀ kọ́lé tàbí ra ọkọ̀ nínú rẹ̀' pasito Joel olasunkanmi lo ṣalaye bee ‎- Lóòótọ́ lowo jáde lẹ́yìn tí mo gbìyànjú láti ṣoògùn owó àmọ́ wọ́n ní mi ò gbọdọ̀ kọ́lé tàbí ra ọkọ̀ nínú rẹ̀' pasito Joel olasunkanmi lo ṣalaye bee Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ipinlẹ Osun mu awọn Afurasí ọmọ ẹgbẹ́ okunkun méjì, wọ́n gba Ìbọn àti Àwọn Ohun ìjà mìíràn lọwọ wọn drivetvnews drivetv news drivetv yoruba drivetv yoruba vlog drivetvyorubavlog