O MA SE O! ATINUKE KAREEM YORUBA MOVIE ACTRESS MI TUN JADE LAYE LEYIN AISAN JEJERE TO BA FINRA
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
O MA SE O! ATINUKE KAREEM YORUBA MOVIE ACTRESS MI TUN JADE LAYE LEYIN AISAN JEJERE TO BA FINRA
5 226 просмотров · 1 день назад
DriveTv Yoruba
15,1 тыс. подписчиков
5 226 просмотров · 1 день назад
O MA SE O! ATINUKE KAREEM YORUBA MOVIE ACTRESS MI TUN JADE LAYE LEYIN AISAN JEJERE TO BA FINRA
Ileṣẹ to ń rí sì ọ̀rọ̀ ẹjọ́ Tinubu pelu esun gbígbé ògùn oloro ni ilẹ̀ amẹ́ríkà tí ṣàlàyé pé àwọn èèyàn kan tí daba fifun Ileṣẹ náà ni milionu meta dọ́là láti panu mo lórí ọ̀rọ̀ esun ọ̀daràn ohun
Gbogbo awọn to nsọ kiri pe ayederu iwé ni a fẹ fi gbé Tani Olorun, wọn o mọ ohun ti wọn nsọ ni o, alaimọkan lo pọ nínú wọn US Imam lo sọrọ jade be sigboro aye
Awakọ taksi ọmọ ilẹ Nàìjíríà ti o togbe tọkọ rẹ fi ya lọ sekupa eniyan kan nílẹ UK ri ẹwọn ọdún mẹfa ati yiyẹra fun ọkọ wiwa fun ọdún mẹjọ gbà nile ẹjọ
Iboosi oo, Inú àpò àṣùwọ̀n owó orí ayélujára 'crypto' ni wọ́n n jí owó ìjọba ìbílẹ̀ pamọ́ sí báyìí o – àjọ EFCC lo figbe ta bee
Portable n parọ o ni mo ge òun jẹ, Irọ lo n pa ana sare ni fun. Charlse Okocha lo sọrọ soke bẹẹ.
Ilé ẹjọ́ tí gbé àlùfáà ijọ́ kan ju sewon lẹ́yìn tí wọn fẹsun kan pé ó kowo bo ọmọ ọmọ rẹ lábẹ́ títí tomo náà fin seje
Primate Ayodele tí kesi àárẹ̀ Tinubu láti gbàgbé ṣáá kejì tí ilé Amẹrikà bá file tú àwọn akọsílẹ̀ Tinubu síta lórí ọ̀rọ̀ ìwà ọ̀daràn gbígbé ògùn oloro
Ìgbìmọ̀ gbogbogboo fún sharia ni Naijiria ti kesi ijoba lati gbe igbésẹ̀ lọ́nà tó bófin mu àti ọ́nà tooto lórí ọ̀rọ̀ ejò àti ìdá dúró El-Rufai
Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ cross river ti fi panpe òfin gbé ọ̀dọ́mokunrin ẹni ọdún mẹrindinlogun kan latari pe òfi ọ̀bẹ gun ọmọ ògùn ọdún kan pá lakoko tí wọ́n ni àríyànjiyàn
O má see óò, Ileṣẹ fíìmù Yorùbá tun kéde ikú ọkàn lára wọn ọṣèrébinrin Atinuke Kareem leyin to ń dojú kọ àìsàn jẹjẹrẹ omu
Atiku ṣèlérí láti satunyewo eto eyawo awọn akẹkọọ àti láti fọ́jú fò àwọn gbèsè eyawo àwọn akẹ́kọ̀ọ́ to ṣe pàtàkì tí àwọn ọmọ Nàìjíríà bá dibo yàn òun gẹ́gẹ́ àárẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà
drivetv
drive tv
drivetvnews
drive tv news
drivetv news
drivetv yoruba
drive tv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog