AGBA OSERE ELESHO NI AISAN JEJERE AWO ARA SKIN CANCER EGBE OSERE TI SORO SOKE LORI IROYIN NAA
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
AGBA OSERE ELESHO NI AISAN JEJERE AWO ARA SKIN CANCER EGBE OSERE TI SORO SOKE LORI IROYIN NAA
2 776 просмотров · 3 дня назад
DriveTv Yoruba
15,1 тыс. подписчиков
2 776 просмотров · 3 дня назад
AGBA OSERE YEMI ELESHO NI AISAN JEJERE AWO ARA SKIN CANCER EGBE OSERE TI SORO SOKE LORI IROYIN NAA
Owo Ogogo o si lọwọ imam agbà ìlú ilaro mo o, a ti gba mílíọ́nù márùndínlọ́gbọ̀n owo Náírà tí Ogogo gbé pamọ sọwọ Ìmáàmù àgbà náà padà - Ẹbí Ogogo lo fohun náà lede bee.
O see ṣe kí àárẹ̀ Tinubu fọ́jú bá ilé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn ìwà ọ̀daràn lẹ́yìn isakoso rẹ gẹ́gẹ́ bí àárẹ̀, Ileṣẹ kan tó wà lórí lede amẹ́ríkà lo ṣàlàyé bẹẹ
Atiku Abubakar ṣèlérí láti san owo awon ijoba ibile sì asunwon wọn tààrà tí àwọn ọmọ Nàìjíríà bá di yàn òun gègé bí àárẹ̀ lodun 2027
Egbẹ osere ANTP tako Ìròyìn pe Àgbà oṣèré Eleso ní àisan Jẹjẹre awo ara skin cancer.
Ṣọọṣi kí ṣe ibi ìpolongo ibo nítorí pé ibi mímọ ni, kosi yẹ kíá sọ di ibi èérí pelu ìwà àìtó òsèlú, Deji Adeyanju lo ṣalaye bee leyin irinajo Peter Obi sì ilé ìjọsìn
Alaye re o lori ìròyìn pe OPay fẹ́ kógbá wọlé ní Naijiria lónìí ọjọ́ kíní oṣù Kẹ́sàn án.
Ilé ẹjọ́ dá ẹjọ́ tí Atiku pé tako àárẹ̀ Tinubu dúró fún ìgbà díẹ̀ látàrí pé Atiku kò tilè fún àárẹ̀ Tinubu ni ìwé ìpéjọ gègé bí òfin seso
- Dokita kan lAbuja wọ gau lori bo se gbà kíndìnrin awọn ọdọkunrin kan pẹlu alaye pe awọn ọdọkunrin náà finu fẹdọ fi kindinrin wọn tọrẹ fun awọn ti wọn nilo rẹ ni.
Ileeṣẹ Ọlọ́pàá ti ṣàlàyé bí wọ́n ṣe doola àwọn agunbaniro mẹ́ẹ̀ẹ́dógún àti àwọn èèyàn mẹ́fà míì lọ́wọ́ àwọn ajínigbé ni ipinlẹ Kogi
drivetv
drive tv
drivetvnews
drive tv news
drivetv news
drivetv yoruba
drive tv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog