A O TI GBA PE ADEMOLA ADELEKE LO WOLE L'OSUN AFI TI A BA SE AWON IWADII WA LABE OFIN ETO IDIBO - APC
DriveTv Yoruba
0:00 / 0:00
A O TI GBA PE ADEMOLA ADELEKE LO WOLE L'OSUN AFI TI A BA SE AWON IWADII WA LABE OFIN ETO IDIBO - APC
5 753 просмотра · 2 недели назад
DriveTv Yoruba
15,1 тыс. подписчиков
5 753 просмотра · 2 недели назад
A O TI GBA PE ADEMOLA ADELEKE LO WOLE L'OSUN AFI TI A BA SE AWON IWADII WA LABE OFIN ETO IDIBO - APC
Bi a ba seni loore ope laadu Gomina Ademola Adeleke dupẹ lọwọ awọn eeyan ipinlẹ Osun leyin to wọlé saa keji gẹgẹ bíi gomina ipinlẹ naa, bee lo gbosuba kare fun Ààrẹ Bola Tinubu.
A o ti le so pe ètò idìbò Ọsun pari sibi ti won lo pari si o, afi ti a ba se awọn ìwádìí wa labe ofin ètò idìbò. Egbẹ oselu APC lo fohun silẹ be leyin ti won lule l'Osun
Kodin ni Aarundinloodunrun awon janduku ti owo ba lakoko idibo gomina ni ipinle Osun..... Ilese Olopa lo kede be
E gbo óòtọ́ọ́ wo lo wa nínú pe àwọn ẹ̀gbọ́n Gómìnà Ademola Adeleke ti já àkóso ìjọba Osun gbà mọ́ ọ lọ́wọ́.
Ọọni tile Ifẹ̀ ni yóò ko àwọn ọba ilẹ̀ Gúúsù Ìwọ̀-Oòrùn sodi lọ síbi ayẹyẹ àṣà ní ìlú Ekiti
Ọkọ Ìyàwó kan ti o pe ara re ni pasitọ dana sun Ìyàwó re mole lo ba n pariwo isẹ esu ni.
Igbesẹ Atiku pelu wíwò Tinubu lọ ilé ẹjọ́ lórí ọ̀rọ̀ àwọn ìwé erí rẹ, Maduabuchi Idam ni igbésẹ̀ to tí kú láti ìbẹ̀rẹ̀ ni igbésẹ̀ naa
Ààrẹ Tinubu fi ikini rẹ ranṣẹ sì gómìnà Adeleke leyin ijawe olubori rẹ nínú idibo to waye ni ipinlẹ osun
Ẹ sọra fun ẹtan ayederu awọn asagbateru irin àjo Hajj o, keeyin Gold o ma lo di panda. àjọ NAHCON lo kilo fawọn èèyàn bee
Igbesẹ Atiku pelu wíwò Tinubu lọ ilé ẹjọ́ lórí ọ̀rọ̀ àwọn ìwé erí rẹ, Maduabuchi Idam ni igbésẹ̀ to tí kú láti ìbẹ̀rẹ̀ ni igbésẹ̀ naa
drivetv
drive tv
drivetvnews
drive tv news
drivetv news
drivetv yoruba
drive tv yoruba
drivetv yoruba vlog
drivetvyorubavlog